From Tap & Earn

From Tap

Lyrics

Mo So Rire lyrics By the anointed Paul Play Dairo

Mo So Rire lyrics By Paul Play Dairo

intro
The remix believe it or not (the remix love)
The remix believe it or not (yeah) believe it or not, believe it or not (yeah)
This is how it should be done (uh, uh)
‘Cause this style (what, what?) how can I make you dance? (c’mon)
PD that’s what you came here for right? (that’s what you came here for, alright, alright)
verse
Ẹlẹda mi mọ di ẹ mú
Mọ diẹ mú
Ẹlẹda mi mọ di ẹ mú, mi ò gbọdọ jabo
Ẹlẹda mi mọ di ẹ mú, baba mọ diẹ mú
Ẹlẹda mi mọ di ẹ mú, mi ò gbọdọ jabo
Mo wà dùpẹ ọrẹ àná, baba mo dùpẹ o
Mo wà dùpẹ ọrẹ ẹni, baba mo dùpẹ o
Mo tún dùpẹ ọrẹ ọlá, baba mo dùpẹ o
Baba mo dùpẹ o, baba mo dùpẹ o
Baba mo dùpẹ o, baba mo dùpẹ
chorus
Bí mo bá ji l’òwúrò kùtùkùtù ma d’orí mí mú
Mo sórí rè o Ẹlẹda mi mo dùpẹ o
Bí mo bá ji l’òwúrò kùtùkùtù ma d’orí mí mú
Mo sórí rè o Ẹlẹda mi mo dùpẹ o, baba
Mo sórí rè o Ẹlẹda mi mo dùpẹ o, baba
Mo sórí rè o Ẹlẹda mi mo dùpẹ o
verse
Ọlọ́run àgbáyé, Ọlọ́run àgbáyé
Ọlọ́run àgbáyé, Ọlọ́run àgbáyé
Iwọ nìkan ni ìgbẹ́kẹ̀lé mí, ìwọ nìkan ni ìgbẹ́kẹ̀lé mí
Baba baba baba baba, Olúwa
B’ọmọdé ba dùpẹ ọrẹ àná, ari omiran gbá
Kò ṣeni tó lè ṣe bí kín ṣe wọ
chorus
Bí mo bá ji l’òwúrò kùtùkùtù ma d’orí mí mú
Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o
Bí mo bá ji l’òwúrò kùtùkùtù ma d’orí mí mú, ah
Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o, baba
Mo sórí rè o Ẹlẹda mi mo dùpẹ o, baba
Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o
verse
Hm oya, hm oya, hm
Eje ka dùpẹ lowo Ọlọ’run, ei
Eje ka dùpẹ lowo Ọlọ’run mo tí sórí rè
Eje ka dùpẹ lowo Ọlọ’run, ei ei ei
Eje ka dùpẹ lowo Ọlọ’run
Ah, easy, woske, ah ah, easy, oje skeskeske
verse
Ẹlẹda mi mọ di ẹ mú
Mọ diẹ mú
Ẹlẹda mi mọ di ẹ mú, baba mi ò gbọdọ jabo
Ẹlẹda mi mọ di ẹ mú, mọ di ẹ mú
Ẹlẹda mi mọ di ẹ mú, mi ò gbọdọ jabo
Ọlọ́run àgbáyé, Ọlọ́run àgbáyé
Ọlọ́run àgbáyé, mi ò gbọdọ jabo
Kò ṣeni tó lè ṣe bí kín ṣe wọ, kò ṣeni tó lè ṣe bí kín ṣe wọ
Ate réré kárí ayé
chorus
Bí mo bá ji l’òwúrò kùtùkùtù ma d’orí mí mú, ah
Mo sórí rè o, Ẹlẹda mi mo dùpẹ o
Bí mo bá ji l’òwúrò kùtùkùtù ma d’orí mí mú
Mo sórí rè o, Ẹlẹda mi mo dùpẹ o
Baba mo dùpẹ o, Baba mo dùpẹ o (Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
Baba mo dùpẹ o, Baba mo dùpẹ (Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
Mo tí sórí rè, baba, mo tí sórí rè, baba o (Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
Mo tí sórí rè, baba, mo tí sórí rè, baba o (Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
chorus
Ate réré kárí ayé (Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
Ate réré kárí ayé o (Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
Bí mo bá ji l’òwúrò kùtùkùtù…(Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
Baba, baba (Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
Baba oṣe, baba oṣe (Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
Mo dùpẹ o, mo dùpẹ o (Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
Mo dùpẹ o lowo ré baba (Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
Mo dùpẹ, mo dùpẹ, mo dùpẹ (Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
(Mo sórí rè o Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)

LEAVE A RESPONSE

Your email address will not be published. Required fields are marked *